Tuesday, July 2, 2019

Typhoid and malaria


PINEAPPLE PEEL 
LIME 9PIECE
ORANGE 2BIG SIZE
LEMON GRASS LEAF
GINGER 2BIG SIZE
GARLIC 10 SMALL PIECE
5lipton tea bag
CORN WATER (omi dun in Yoruba)
Cooked all together, took 1cup to bed and I work up feeling relief, passing it out tru urine.
Dosage 1cup 3x daily.

OSHOLE TODAJU


Ori eye osin kan , odidi igbin toba gbodo daada kan, ewe omisimisi gogoro, ewe ogo, ao jo papo, ao lo kunna daada, aoma firo ekuru fun fun je laarin oru.

AWORO


Ori ako ati abo alangba ao jo pelu odidi atare kan, aofi iyo die si, ao ro sinu ato ao so ko si inu ile abi shop wa, ao ni de lenu o.

ISE ANU


A o fi oti gbo ewe oriji ati ajeobale, ao a tu milk si odi mimu.

AWEBI WEPE DANU


Epo obo die, ewe bomubomu, ao gun mo ose dudu, ao lo fi we lodo lekan soso.

IPARA ANU


Ao wa ewe anu gbigbe,ao lo pelu kafura pelebe, ao lo papo, ao da sinu ipara. Ao ma fi para.

ASEJE OWO


Ewe abamoda kan, ewe ogbo kan, ao lo pelu ata ijosi ao fi se igbin nla kan je lepo niyo.

AJEGUN


Egbo lapalapa ati odidi atare kan, ao jo papo, ao lo kuna daada, ao ma fi epo pupu la ninu awo ipese.

ITUWO AWON AGBALAGBA


Ao gun epo obo mose, A o fi epo pupa po ose naa. A o ko sinu fitila oloju kan, A o ma fi ose naa we ni gbogbo igba

OSE ASINA


Ewe Akoko oojo 21 eyi ti ko lu rara . Ao fi rori sun moju, ti ile ba ti mo dada A o lo po mo taba mimu, A o po mose eyikeyi. A o ma fi we.

OSHO AJE ORUN


ori olongbo kan
Ori oka tolase lenu kan
Ori ere tolase lenu kan
Egungun ori esin
Irun ori afin
Awo tanganran funfun
#1000 tabi $100
Ose dudu die
Ewe orijin oojo
SISERE:ao gun ewe orijin kuna dada ao walo awon eronja yen leyo kookan ti yio kuna ao wa gun papo ao da ose lelori ao tun gun dada ao fi owo #1000 tuntun tele awo tanganran funfun tabi $100 dollar yen ao ko ose yi le owo yen lori ninu awo ao mawe larolaro pelu ofore re
OFORE:agbele jifa niti oka
Agbele jifa niti ere
Ori esin ki buru koma ri eni sin
Atile atona la fi njin ologbo
Ewe orijin loni ki eyin tokunrin tobinrin omo araye ki ewa fowo owo yin jinmi loni
Tori ti afin bawolu gbogbo oju ni nwo odo emi L omo L ni ki omo araye mako owo won bo ooo (Aniyan)
AKIYESI: akogbodo we ose yi ni ojo Wednesday ati Saturday ooo
Odaju gidi gan walahi asiri wa yio ma bo ao siri owo gidi lasiko yen
Eje kia Lo ko owo le ise yi walahi odaju gidi gan ni ooo
Tested and confirmed lati owo emi 

AWURE TI A FI NDI ENI NLA ATI OLOKIKI


Eran erin Eran efonEwe sapo Ewe akoko Eku eda 1 Odidi atare 1 Eyele funfun1 Sise re... A o jo gbogboawon nkan wonyii papo, yato si eyele yen, a o loo kunna,a o roo sinu ado ide kan, a o pa eyele yii fi bo ado yen, a o gbeesinu apo aso funfunkan, a o maa fi ekuru funfunbo ado naa ni every week, a o maa fi eyele funfunboo ni osoosu. OFO RE... Agbelegbola3×, agb'odedegbayi 3×, kekere labi erin sinu igboti erin di nla, kekere labi efonsinu odan, ti efonfi di nla, edumarewa so emi L omo L di eni nla, bi ogburugburuba lale hu, a gbearin oko igi di nla, ifa so emi L omo L di nla, a kii fi ewekewejoyeleyin akoko, eledumarewa fi emuL omo L se olu, eda ki o dari opolopoowo temiL omo L wa bami, eda ki o dari owo rere, ile rere, motorrere, etcorigunmereerinaiye wa si odo emi L omo L, loni ati titi laelae. Lilo re... A o maa fi ebuyii sa ori ni emeerinlaarin osukan.

OSE ANU TO DAJU

Ewe iyalode funfun21, pali sugaronikoroodidi kan ao gun gbogbosugaryen ati ewe yen ti yio kunnadada Ao pomoose lux tabi joy 6,Ao ko sinu ike white ao se adura si dada ao depa fun 9days ki a to herewiwe re laro kutu odaju

making some ebos..(sacrifice)

 it is the way to
clean your way from evil doer ...also to know
more about What is going in your life and things
affecting you.. and how to conquer them....still in
progress ifa for the new your...
ifa divinations and sacrifice...
akose.
ikin ifa dida..
provisions for iyami ..(witches )
and also the class online learning ...
also some we can not listed ...
ifa will bless us ase ooooo.

awure ise wiwa


Ewe alupaida mefa, akeke ati kuluso a o jo po a o po mo ose dudu a p ma fi we lo si ibi ti atin wa ise
Odaju

awure owo nla


Akuko adie kan,ewe tanaposo 50,ati opolopo iyere a o lo a o fi se adie na je.
Akiyesi:ori ati ese adia na a o re mile

Eyonu tipatipa


Omunu ewe ewuro oojo tikolu,a o gun mose dudu a o da epo pupa le lori pelu ori ninu ike funfun a o ro papo a o ma fi we

OGUN EYONU AYÉ

Ewé òmísínminsìn afaara Oyin padi atare kan ao jo papo ao ma busi atẹlẹwọ pẹlú iyo isebe dee ao ma sa durasi kato da se nu ao muomi sii odaju

OGUN EYONU AGBA TODAJU

Bi o ba se igba eniyan won yio dari jin e lagbara olorun: ewe aanu, ewe orijin, ewe ooyo, ewe ajeofole, ao toju epo pupa die, ori die, adi die, ao gbe won sinu oorun lotooto ti won o fi yo tan. Ao gun gbogbo eroja yen papo pelu ose dudu ao wa kan die die ninu epo, ori ati adi yen si, ao po papo. Ofo re: ewe olusaanu loni ki e saanu mi, ewe orijin loni ki e foro temi jinmi, ewe ajeofole loni ki oran gbogbo o fomi ru, ooyo loni ki e maa yonu simi, bi epo ba foju kan oorun ti inu re yo ni, bi ori ba foju kan oorun ti inu re yo ni, bi adi ba foju kan oorun ti inu re yo ni.