Tuesday, July 2, 2019

AWURE TI A FI NDI ENI NLA ATI OLOKIKI


Eran erin Eran efonEwe sapo Ewe akoko Eku eda 1 Odidi atare 1 Eyele funfun1 Sise re... A o jo gbogboawon nkan wonyii papo, yato si eyele yen, a o loo kunna,a o roo sinu ado ide kan, a o pa eyele yii fi bo ado yen, a o gbeesinu apo aso funfunkan, a o maa fi ekuru funfunbo ado naa ni every week, a o maa fi eyele funfunboo ni osoosu. OFO RE... Agbelegbola3×, agb'odedegbayi 3×, kekere labi erin sinu igboti erin di nla, kekere labi efonsinu odan, ti efonfi di nla, edumarewa so emi L omo L di eni nla, bi ogburugburuba lale hu, a gbearin oko igi di nla, ifa so emi L omo L di nla, a kii fi ewekewejoyeleyin akoko, eledumarewa fi emuL omo L se olu, eda ki o dari opolopoowo temiL omo L wa bami, eda ki o dari owo rere, ile rere, motorrere, etcorigunmereerinaiye wa si odo emi L omo L, loni ati titi laelae. Lilo re... A o maa fi ebuyii sa ori ni emeerinlaarin osukan.

No comments:

Post a Comment